Serena Williams
Ni 2014 | |
Orílẹ̀-èdè | United States |
---|---|
Ibùgbé | Palm Beach Gardens, Florida, United States[1] |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹ̀sán 1981 Saginaw, Michigan, United States |
Ìga | 5 ft 9 in (1.75 m)[1] |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | September 24, 1995 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Owo-otun (igbaeyin olowo-meji) |
Ẹ̀bùn owó | US$ 73,293,424[2] (1st all-time among women athletes and 4th all-time among tennis athletes)[3] |
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | serenawilliams.com |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 783–130 (85.76%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 73 WTA[1] (4th in overall rankings) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (July 8, 2002) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1 (June 6, 2016)[4] |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | Ay (2003, 2005, 2007, 2009, 2010, 2015, 2017) |
Open Fránsì | Ay (2002, 2013, 2015) |
Wimbledon | Ay (2002, 2003, 2009, 2010, 2012, 2015, 2016) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1999, 2002, 2008, 2012, 2013, 2014) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | Ay (2001, 2009, 2012, 2013, 2014) |
Ìdíje Òlímpíkì | Ẹ̀ṣọ́ wúrà (2012) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 169-22 (89.1%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 22 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (June 7, 2010) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 64 (September 23, 2013) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | Ay (2001, 2003, 2009, 2010) |
Open Fránsì | Ay (1999, 2010) |
Wimbledon | Ay (2000, 2002, 2008, 2009, 2012, 2016) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1999, 2009) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje WTA | SF (2009) |
Ìdíje Òlímpíkì | Ẹ̀ṣọ́ wúrà (2000, 2008, 2012) |
Àdàpọ̀ Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 27–3 (90%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 2 |
Grand Slam Mixed Doubles results | |
Open Austrálíà | F (1999) |
Open Fránsì | F (1998) |
Wimbledon | Ay (1998) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1998) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Fed Cup | Ay (1999) |
Hopman Cup | Ay (2003, 2008) |
Last updated on: August 31, 2015. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Tẹ́nìs àwọn obìnrin | |||
---|---|---|---|
Adíje fún USA | |||
Wúrà | 2000 Sydney | Ẹniméjì | |
Wúrà | 2008 Beijing | Ẹniméjì | |
Wúrà | 2012 London | Ẹnìkan | |
Wúrà | 2012 London | Ẹniméjì |
Serena Jameka Williams (ojoibi September 26, 1981) je agba boolu Tenis omo orile-ede Amerika lowolowo to wa Eniipo kinni lagbaye ninu idije enikan ati Eniipo keji ninu idije enimeji pelu egbon re Venus Williams(12/8/10). Ijose Tenis awon Obinrin (WTA) ti fisipo kini lagbaye ni igba otooto marun. O tun ipo kinni gba fun igba karun ni ojo 2 Osu Kokanla 2009. O koko bo si ipo kinni lagbaye ni ojo 8 Osu Kejo 2002. Ni ojo 3 Osu Keje 2010, o di eni kefa lori akojo awon oludijeakoko olokikijulo gbogbo igba lailai.[5]
Williams ni oludijeakoko lowolowo ni idije enikan ati enimeji awon obinrin ni Open Australia, oludijeakoko lowolowo idije enikan ni Wimbledon, ati ni idije enimeji awon obinrin ni Open Faranse ati ni Open Amerika. Awon ife-eye Grand Slam mejilelogbon to gba fun ni ipo kefa lori akojo gbogbo igba lailai: 17 ni idije awon obinrin enikan, 13 ni idije awon obinrin enimeji, ati 2 ni idije adapo enimeji. Ohun ni agbayo laipe yi, obinrin abi okunrin, to gba gbogbo awon ife-eye Grand Slam mereerin leekanna, ati obinrin ikarun lailai to se be. Awon ife-eye Grand Slam 17 re ni ikefa lori akojo gbogbo igba lailai.[6] Williams je ikerin bii awon ife-eye Grand Slam awon obinrin to gba n'Igba Open, leyin Steffi Graf (ife-eye 22) ati Chris Evert ati Martina Navratilova (ife-eye 18).[6] O ti gba awon ife-eye Grand Slam ni idije enikan, awon obinrin enimeji ati adapo enimeji ju obinrin agbayo miran lo lowolowo.
Williams ti gba eso wura Olimpiki ikan ninu idije awon obinrn enikan ati meta ninu idije awon obinrin enimeji pelu egbon re Venus Williams.[7] Williams ti gba ebun owo fun ise ju obinrin elere-idaraya miran lo lailai.[8] Williams ni aburo Venus Williams to ti wa ni ipo kinni lagbaye tele. Won ti ba ara won gbayo nigba 23 idije alagbase lati 1998, Serena bori ni 17 awon idije wonyi titi di Osu Kewa 2013. Titi di Osu Keje 2009, won ti pade ni opin idije Grand Slam mejo, Serena bori ni emefa. Larin Open Faranse 2002 ati Open Australia 2003, won pade ni opin awon idije enikan gbogbo Grand Slam mererin, igba akoko ni igba open ti awon oludije meji kanna dije fun opin Grand Slam ni titelentele. Awon mejeji ti gba ife-eye Grand Slam 12 idije enimeji bi ikanna.
Ibere igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Williams je bibi ni Saginaw, Michigan fun Richard Williams ati Oracene Price. O je omo Afrika Amerika, ohun si ni omo tokerejulo larin awon omobinrin Oracene: Yetunde (o ku ni 14 Osu Kesan 2003), Lyndrea ati Isha Price, ti won je iyekan re arabinrin ati Venus to je egbon re arabinrin.[1] Iya won to won dagba bi ijo awon Ajeri Jehovah. Nigba ti awon omo si kere, ebi won ko lo si adugbo itosi Los Angeles Compton, nibi ti Serena ti bere sini gba tenis nigba to je omo odun merin.[9] Ile-eko lati ile ni ohun ati egbon Venus gba.[10] Torie lo se je pe doni awon obi re ni won ko ni tenis gbigba.[1]
Ebi Williams ko lo si West Palm Beach ni Florida lati Compton nigba to je omo odun mesan ko le ba le lo si akademi tenis ti Rick Macci, to fu ni eko ere-idarayan yioku. Macci ri ebun eleda awon arabinrin Williams. Bo tile je pe nigba miran ko fenuko mo baba Williams o iteriba fun pe "o toju awon omobinrin re bi omode, o si gba won laaye lati wuwa bi omode".[11] Richard dawo riran awon omo re lo si awon idije omode nigba ti Williams je omo odun 10, nitoripe o je ki won o se ero lati koju si eko won. Idi miran tun ni nitori eya, o gbo pe awon obi agbayo alawofunfun unsoro buruku nipa awon arabinrin Williams nigba idije.[12] Nigba yi, Williams ni record 46–3 lori irinkiri idije awon odo ti Ijose Tenis Orile-ede Amerika, ohun lo si je Eni akoko larin awon agbayo tomo odun won koju 10 lo ni Florida.[13] Ni 1995, Richard mu awon omo re kuro ni akademi Macci, latigba na lo ohun lo ti unse eko ere-idaraya fun won. Nigba ti won bere lowo re ni 2000 boya nipa titele ona ti awon yioku gba nipa gbayo nigbogbo igba ni awon idije odo ko ba fun ni anfani, Williams dahun pe "Onikaluku unse ohun otooto. Emi ati Venus gba ona miran, o ja fun wa."[13]
Ajise alagbase
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]1995-98: Ibere alagbase
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Idije alagbase akoko Williams waye ni Osu Kesan 1995 nibi idije Bell Challenge ni Quebec City. O pofo ayo akoko si Eniipo 149 Lagbaye, Annie Miller larin wakati kan ayo o si gba US$240 bi ebun owo.
Williams ko gba ayo kankan ni 1996. Ni 1997 o pofo ni ayo ikopa meta ni idije meta ko to dipe o bori ninu ayo akoko re ni Osu Kokanla ni Ameritech Cup Chicago. Nigbana bi Eniipo 304 lagbaye, o bori Eniipo 7 Mary Pierce ati Eniipo 4 Monica Seles, eyi fun ni ibori re akoko lori awon agbayo onipo mewa akoko, o si di agbayo onipo to kerejulo ni igba open to bori awon olodi ni ipo mewa akoko ninu idije kan.[1] Nigbeyin o pofo ni ikejiopin si Eniipo 5 lagbaye Lindsay Davenport. O pari 1997 ni ipo 99.
Williams began 1998 at the Medibank International Sydney. As a qualifier ranked World No. 96, she defeated World No. 3 Davenport in the quarterfinals before losing to Arantxa Sánchez Vicario in the semifinals. Williams made her debut in the main draw of a Grand Slam tournament at the Australian Open, where she defeated sixth seeded Irina Spîrlea in the first round before losing to sister Venus in the second round, in the sisters' first professional match.[14] Williams reached six other quarterfinals during the year but lost all of them, including her first match against World No. 1 Martina Hingis at the Lipton International Players Championships in Key Biscayne and her second match against Venus at the Italian Open in Rome. She failed to reach the quarterfinals of any Grand Slam tournament the remainder of the year, losing in the fourth round of the French Open to Sánchez Vicario and the third round of both Wimbledon and the US Open, to Virginia Ruano Pascual and Spîrlea, respectively. She did, however, win the mixed doubles titles at Wimbledon and the US Open with Max Mirnyi, completing the Williams family's sweep of the 1998 mixed doubles Grand Slam tournaments. Williams won her first professional title in doubles in Oklahoma City with Venus, becoming the third pair of sisters to win a WTA title.[1] The Williams sisters won two more doubles titles together during the year. Serena finished the year ranked World No. 20 in singles.
1999–2001: Didi eni agbayo akoko 10
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]2002–03: Awon ife-eye Grand Slam telentele
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]2004–06: Ipalara ati aibaramu igbayo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]2007–08: Pipada si top 10
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]2009: Pipada si Eniipo 1 lagbaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]2010: O duro si ipo kinni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon ife-eye to gba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Idije enikan (73)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]No. | Ojoodun | Idije | Alátàkò | Esi ayo |
1. | 22 Osu Keji 1999 | Paris, Fransi | Amélie Mauresmo | 6:2, 3:6, 7:6 |
2. | 1 Osu Keta 1999 | Indian Wells, USA | Steffi Graf | 6:3, 3:6, 7:5 |
3. | 9 Osu Kejo 1999 | Los Angeles, USA | Julie Halard-Decugis | 6:1, 6:4 |
4. | 30 Osu Kejo 1999 | Open Amerika, New York, USA | Martina Hingis | 6:3, 7:6 |
5. | 27 Osu Kesan 1999 | Ife-eye Grand Slam, München, Jemani | Venus Williams | 6:1, 3:6, 6:3 |
6. | 14 Osu Keji 2000 | Hannover, Jemani | Denisa Chládková | 6:1, 6:1 |
7. | 7 Osu Kejo 2000 | Los Angeles, USA | Lindsay Davenport | 4:6, 6:4, 7:6 |
8. | 2 Osu Kewa 2000 | Tokio, Japan | Julie Halard-Decugis | 7:5, 6:1 |
9. | 1 Osu Keta 2001 | Indian Wells, USA | Kim Clijsters | 4:6, 6:4, 6:2 |
10. | 13 Osu Kejo 2001 | Toronto, Kanada | Jennifer Capriati | 6:1, 6:7, 6:3 |
11. | 29 Osu Kewa 2001 | Idije WTA, München, Jemani | Lindsay Davenport | kò yọjú |
12. | 25 Osu Keji 2002 | Scottsdale, USA | Jennifer Capriati | 6:2, 4:6, 6:4 |
13. | 18 Osu Keta 2002 | Miami, USA | Jennifer Capriati | 7:5, 7:6 |
14. | 13 Osu Karun 2002 | Rome, Italy | Justine Henin | 7:6, 6:4 |
15. | 27 Osu Karun 2002 | Open Fransi, Paris, Fransi | Venus Williams | 7:5, 6:3 |
16. | 24 Osu Kefa 2002 | Wimbledon, London, UK | Venus Williams | 7:6, 6:3 |
17. | 26 Osu Kejo 2002 | Open Amerika, New York, USA | Venus Williams | 6:4, 6:3 |
18. | 16 Osu Kesan 2002 | Tokio, Japan | Kim Clijsters | 2:6, 6:3, 6:3 |
19. | 9 Osu Kesan 2002 | Leipzig, Jemani | Anastassia Myskina | 6:3, 6:2 |
20. | 13 Osu Kinni 2003 | Open Australia, Melbourne, Australia | Venus Williams | 7:6, 3:6, 6:4 |
21. | 3 Osu Keji 2003 | Paris, Frankreich | Amélie Mauresmo | 6:3, 6:2 |
22. | 17 Osu Keta 2003 | Miami, USA | Jennifer Capriati | 4:6, 6:4, 6:1 |
23. | 23 Osu Kefa 2003 | Wimbledon | Venus Williams | 4:6, 6:4, 6:2 |
24. | 22 Osu Keta 2004 | Miami, USA | Elena Dementieva | 6:1, 6:1 |
25. | 20 Osu Kesan 2004 | Beijing, Saina | Svetlana Kuznetsova | 4:6, 7:5, 6:4 |
26. | 29 Osu Kinni 2005 | Open Australia, Melbourne, Australia | Lindsay Davenport | 2:6, 6:3, 6:0 |
27. | 27 Osu Kinni 2007 | Open Australia, Melbourne, Australia | Maria Sharapova | 6:1, 6:2 |
28. | 31 Osu Keta 2007 | Miami, USA | Justine Henin | 0:6, 7:5, 6:3 |
29. | 9 Osu Keta 2008 | Bangalore, India | Patty Schnyder | 7:5, 6:3 |
30. | 5 Osu Kerin 2008 | Miami, USA | Jelena Janković | 6:1, 5:7, 6:3 |
31. | 20 Osu Kerin 2008 | Charleston, USA | Vera Zvonareva | 6:4, 3:6, 6:3 |
32. | 7 Osu Kesan 2008 | Open Amerika, New York, USA | Jelena Janković | 6:4, 7:5 |
33. | 30 Osu Kinni 2009 | Open Australia, Melbourne, Australien | Dinara Safina | 6:0, 6:3 |
34. | 4 Osu Keje 2009 | Wimbledon, London, UK | Venus Williams | 7:6, 6:2 |
35. | 1 Osu Kokanla 2009 | Idije WTA, Doha, Katar | Venus Williams | 6:2, 7:64 |
36. | 30 Osu Kinni 2010 | Open Australia, Melbourne, Australia | Justine Henin | 6:4, 3:6, 6:2 |
37. | 3 Osu Keje 2010 | Wimbledon, London, UK | Vera Zvonareva | 6:3, 6:2 |
38. | 31. Osu Keje 2011 | Stanford, USA | Marion Bartoli | 7:5, 6:1 |
39. | 14 Osu Kejo 2011 | Toronto, Kanada | Samantha Stosur | 6:4, 6:2 |
40. | 8 Osu Kerin 2012 | Charleston, USA | Lucie Safarova | 6:0, 6:1 |
41. | 13 Osu Karun 2012 | Madrid, Spain | Victoria Azarenka | 6:1, 6:3 |
42. | 7 Osu Keje 2012 | Wimbledon, London, UK | Agnieszka Radwanska | 6:1, 5:7, 6:2 |
43. | 15 Osu Keje 2012 | Stanford, USA | Coco Vandeweghe | 7:5, 6:3 |
44. | 4 Osu Kejo 2012 | Idije Olympiki, London | Maria Sharapova | 6:0, 6:1 |
45. | 10 Osu Kesan 2012 | Open Amerika | Victoria Azarenka | 6:2, 2:6, 7:5 |
46. | 28 Osu Kewa 2012 | Idije WTA, Istanbul, Turkey | Maria Sharapova | 6:4; 6:3 |
47. | 5 Osu Kinni 2013 | Brisbane, Australia | Anastasia Pavlyuchenkova | 6:2, 6:1 |
48. | 30 Osu Keta 2013 | Miami, USA | Maria Sharapova | 4:6, 6:3, 6:0 |
49. | 7 Osu Kerin 2013 | Charleston, USA | Jelena Janković | 3:6, 6:0, 6:2 |
50. | 12 Osu Karun 2013 | Madrid, Spain | Maria Sharapova | 6:1, 6:4 |
51. | 19 Osu Karun 2013 | Rome, Italy | Victoria Azarenka | 6:1, 6:3 |
52. | 8 Osu Kefa 2013 | Open Fransi, Paris, Fransi | Maria Sharapova | 6:4, 6:4 |
53. | 21 Osu Keje 2013 | Bastad, Sweden | Johanna Larsson | 6:4, 6:1 |
54. | 11 Osu Kejo 2013 | Toronto, Kanada | Sorana Cirstea | 6:2, 6:0 |
55. | 08 Osu Kesan 2013 | Open Amerika | Victoria Azarenka | 7:5, 6:7, 6:1 |
56. | 06 Osu Kewa 2013 | Beijing, Shaina | Jelena Janković | 6:2, 6:2 |
57. | 27 Osu Kewa 2013 | Idije WTA, Istanbul, Turkey | Li Na | 2:6; 6:3; 6:0 |
58. | 4 Osu Kinni 2014 | Brisbane, Australia | Victoria Azarenka | 6:4, 7:5 |
59. | 29 Osu Keta 2014 | Miami, USA | Li Na | 7:5, 6:1 |
60. | 18 Osu Karun 2014 | Rome, Italy | Sara Errani | 6:3, 6:0 |
61. | 3 Osu Kejo 2014 | Stanford, USA | Angelique Kerber | 7:6, 6:3 |
62. | 17 Osu Kejo 2014 | Cincinnati, USA | Ana Ivanovic | 6:4, 6:1 |
63. | 07 Osu Kesan 2014 | Open Amerika | Caroline Wozniacki | 6:3, 6:3 |
64. | 26 Osu Kewa 2014 | Idije WTA, Singapore | Simona Halep | 6:3; 6:0 |
65. | 31 Osu Kinni 2015 | Open Australia, Melbourne, Australia | Maria Sharapova | 6:3, 7:6 |
66. | 4 Osu Kerin 2015 | Miami, USA | Carla Suarez Navarro | 6:2, 6:0 |
67. | 6 Osu Kefa 2015 | Open Fransi, Paris, Fransi | Lucie Safarova | 6:3, 6:7, 6:2 |
68. | 11 Osu Keje 2015 | Wimbledon, London, UK | Garbine Muguruza | 6:4, 6:4 |
69. | 23 Osu Kejo 2015 | Cincinnati, USA | Simona Halep | 6:3, 7:6 |
70. | 15 Osu Karun 2016 | Rome, Italy | Madison Keys | 7:6, 6:3 |
71. | 09 Osu Keje 2016 | Wimbledon, London, UK | Angelique Kerber | 7:5, 6:3 |
72. | 28 Osu Kinni 2017 | Open Australia, Melbourne, Australia | Venus Williams | 6:4, 6:4 |
73. | 12 Osu Kinni 2020 | Auckland Open, New Zealand | Jessica Pegula | 6:3, 6:4 |
Igbese leyin tenis
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aso oge
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Faaji
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ipin ni Miami Dolphins
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ore
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ikowe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon Ebun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 1.6 Serena Williams ní Ìjọṣepọ̀ Tẹ́nìs àwọn Obìnrin Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "WTA profile" defined multiple times with different content - ↑ "Career Prize Money Leaders" (PDF). Women's Tennis Association. 12 August 2013. Retrieved 12 August 2013.
- ↑ "Serena Williams". Forbes.com. Retrieved June 20, 2013.
- ↑ "Women's Tennis Rankings - Rankings as of 21 April 2014". WTA Tennis. WTA Tour. Retrieved April 21, 2014.
- ↑ "Serena Williams Wins at Wimbledon, Tops King With 13th Grand Slam Title". Bloomberg Newsurl=http://www.bloomberg.com/news/2010-07-03/serena-williams-wins-at-wimbledon-tops-king-with-13th-grand-slam-title.html. 2010-07-03.
- ↑ 6.0 6.1 Hickman, Craig (January 30, 2010). "Serena Williams Wins Australian Open". The Huffington Post. Retrieved January 30, 2010.
- ↑ "Williams sisters net gold in doubles, beating Spaniards in final". ESPN. August 17, 2008. Retrieved April 22, 2009.
- ↑ "Serena sets career prize money mark". ESPN. January 30, 2009. Retrieved April 22, 2009.
- ↑ "Bio – Serena Williams". serenawilliams.com. Archived from the original on March 9, 2009. Retrieved April 29, 2009.
- ↑ "Successful & Famous People that were Homeschooled". sharebradenton.homestead.com. Retrieved April 22, 2009.
- ↑ Kaufman, Michelle (April 22, 2007). "Venus, Serena reflect as they prepare for Fed Cup". blackathlete.net. Archived from the original on July 8, 2012. Retrieved April 22, 2009.
- ↑ Peyser, Marc; Samuels, Allison (August 24, 1998). "Venus And Serena Against The World". Newsweek. Newsweek, Inc. Archived from the original on January 19, 2012. Retrieved April 19, 2009.
- ↑ 13.0 13.1 Edmonson, 2005, Venus and Serena Williams, p. 46–47.
- ↑ "Head to Head – Serena Williams vs Venus Williams". WTA Tour, Inc. Archived from the original on February 23, 2009. Retrieved April 22, 2009.
Àjápọ̀ òde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Find more about Serena Williams on Wikipedia's sister projects: | |
Images and media from Commons | |
Quotations from Wikiquote |
- Pages using duplicate arguments in template calls
- Pages with reference errors
- Pages using web citations with no URL
- Pages using citations with accessdate and no URL
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1981
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ará Amẹ́ríkà
- Àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà
- Àwọn agbá tẹ́nìs ará Amẹ́ríkà
- Àwọn ayọrí Open Austrálíà
- Àwọn ayọrí Open Fránsì
- Àwọn ayọrí Ìdíje Wimbledon
- Àwọn ayọrí Open Amẹ́ríkà
- Àwọn tó gba ẹ̀ṣọ́ wúrà Òlímpíkì fún Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà