Rashidat Sadiq
Ìrísí
Rashidat Odun Sadiq(tí a bí ní ọjọ́ kẹta osù kínní ọdún 1981 ní ìlú Ìbàdàn) jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù omo orílẹ̀-ède Nàìjíríà. [1] Ó gbábọ́ọ̀lù ní ilẹ̀ Amẹrika pẹ̀lú University of Connecticut Huskies àti Oklahoma State Cowgirls . Ó tún gbábọ́ọ̀lù pẹ̀lú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní 2004 Summer Olympic Games àti 2006 Commonwealth Games .
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Rashidat Sadiq at WNBA.com