Oprah Winfrey
Oprah Winfrey | |
---|---|
Winfrey ni ọdun 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Orpah Gail Winfrey 29 Oṣù Kínní 1954 Kosciusko, Mississippi, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Tennessee State University (BA) |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1973–present |
Works | Media projects |
Title | Àdàkọ:Indented plainlist |
Political party | Independent |
Alábàálòpọ̀ | Stedman Graham (1986–present) |
Àwọn ọmọ | 1[lower-alpha 1][1] |
Awards | Full list |
Website | oprah.com |
Signature | |
Oprah Gail Winfrey ( /ˈoʊprə/; orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Orpah Gail Winfrey;[2] a bi ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdun 1954) jẹ́ asọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ ìmóhùnmáwòrán, òsèrẹ́binrin àti Olùkọ̀wé ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Àwọn ènìyàn mọ́ fún àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀ lórí The Oprah Winfrey Show, èyí tí wọ́n ma ń gbé sí afẹ́fẹ́ láti Chicago, ìwọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀ orí ìmóhùnmáwọ́ràn fún ọdun meedọ́gbọ̀n, láti ọdun 1986 sí ọdun 2011.[3][4] Àwọn ènìyàn fún Oprah ní orúkọ "Queen of All Media",[5] Òun ni ará Africa mó Amerika tí olówó julọ ni ayé òde òní.[6][7] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni wọ́n ti pé ní obìnrin tí ó níyì julọ ní àgbáyé.[8][9]
Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Orpah Gail Winfrey ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdun 1954; orúkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ ni Orpah àwọn òbí rẹ̀ fun ní orúkọ yìí tẹ̀lẹ́ ẹnìkan nínú ìwé Rutu ti inú ìwé mímọ́, orúkọ yìí sì ni ó wà lórí ìwé ẹrí ìbí rẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn ma ń ṣì orúkọ rẹ̀ pè, tí wón sì ma ń pè ní "Oprah".[2][10] Ìyá tí ó bí jẹ́ omidan tí kò tí gbéyàwó, ó bi ní Kosciusko, Mississippi.[11]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Oprah Winfrey in Melbourne for Australian tour 2015 spreads a message of love, reveals lost child". News.com.au. http://www.news.com.au/national/victoria/oprah-winfrey-in-melbourne-for-australian-tour-2015-spreads-a-message-of-love-reveals-lost-child/news-story/88f87e6fe05a940399db9450a876cfab.
- ↑ 2.0 2.1 "Oprah Winfrey Biography and Interview". achievement.org. American Academy of Achievement.
Winfrey has said in interviews that 'my name had been chosen from the Bible. My Aunt Ida had chosen the name, but nobody really knew how to spell it, so it went down as "Orpah" on my birth certificate, but people didn't know how to pronounce it, so they put the "P" before the "R" in every place else other than the birth certificate. On the birth certificate it is Orpah, but then it got translated to Oprah, so here we are.'
- ↑ "Oprah Winfrey signs with King World Productions for new three-year contract to continue as host and producer of "The Oprah Winfrey Show" through 2010–2011" (Press release). King World Productions. August 4, 2004. Archived from the original on February 10, 2007. Retrieved September 24, 2009.
- ↑ "Oprah Winfrey". Biography (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). February 17, 2021. Retrieved March 5, 2022.
- ↑ Oswald, Brad (January 26, 2010). "Yes, she's Queen of all Media, but to Discovery, she's Life itself". Winnipeg Free Press. http://www.winnipegfreepress.com/opinion/columnists/yes-shes-queen-of-all-media-but-to-discovery-shes-life-itself-82678662.html.
- ↑ Denenberg, Dennis; Roscoe, Lorraine (September 1, 2016) (in en). 50 American Heroes Every Kid Should Meet (2nd Revised ed.). Millbrook Press. ISBN 9781512413298. https://books.google.com/books?id=ulC6DAAAQBAJ&q=oprah+richest+african+of+the+20th+century&pg=PA104.
- ↑ Miller, Matthew (May 6, 2009). "The Wealthiest Black Americans". Forbes. https://www.forbes.com/2009/05/06/richest-black-americans-busienss-billionaires-richest-black-americans.html.
- ↑ Meldrum Henley-on-Klip, Andrew (January 3, 2007). "'Their story is my story' Oprah opens $40m school for South African girls". The Guardian (UK). https://www.theguardian.com/media/2007/jan/03/broadcasting.schoolsworldwide.
- ↑ "The most influential US liberals: 1–20". The Daily Telegraph (London). October 31, 2007. https://www.telegraph.co.uk/news/worldnews/1435442/The-most-influential-US-liberals-1-20.html.Àdàkọ:Cbignore
- ↑ Winfrey has said in interviews that "my name had been chosen from the Bible. My Aunt Ida had chosen the name, but nobody really knew how to spell it, so it went down as 'Orpah' on my birth certificate, but people didn't know how to pronounce it, so they put the 'P' before the 'R' in every place else other than the birth certificate. On the birth certificate it is Orpah, but then it got translated to Oprah, so here we are." "Oprah Winfrey Interview". Academy of Achievement. January 21, 1991. Archived from the original on January 19, 2016. Retrieved August 25, 2008. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:1
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found
- Pages with reference errors
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages with citations using unsupported parameters
- Biography with signature
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1954
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà
- Àwọn olówó
- Àwọn òṣeré fílmù ará Amẹ́ríkà
- Pages with reference errors that trigger visual diffs