Nikki Giovanni
Ìrísí
Nikki Giovanni | |
---|---|
Nikki Giovanni un soro ni Yunifasiti Emory, 2008 | |
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kẹfà 1943 Knoxville, Tennessee |
Iṣẹ́ | Olukowe, ako-ewi, alakitiyan, olukowe |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Amerika |
Ìgbà | 1960s–2024 |
Website | |
nikki-giovanni.com |
Yolande Cornelia "Nikki" Giovanni, Jr.[1][2] (ibi June 7, 1943 o si ku ni Oṣu kejila ọjọ 10, ọdun 2024) je ako-ewi, olukowe, alawiso, alakitiyan, ati oluko ara Amerika. Ikan ninu awon akoewi to gbajumojulo lagbaye,[2] ninu awon ise re ni awon iwe ewi, awo-orin ewi, ati awon ayoka orisirisi ti won da lori eya, oro awujo ati iwe omode. O ti gba opolopo ebun, ninu won ni Ebun Eso Langston Hughes, Ebun Eniyan NAACP. Won ti yan fun Ebun Grammy, fun awo-orin re The Nikki Giovanni Poetry Collection.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
\
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nikki Giovanni", Biography.com.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Jane M. Barstow, Yolanda Williams Page (eds), "Nikki Giovanni", Encyclopedia of African American Women Writers (Greenwood Publishing Group, 2007), p. 213.