Jump to content

Maya Angelou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Maya Angelou
Angelou in Oṣù Kejì 4, 2013
Ọjọ́ ìbíMarguerite Annie Johnson
(1928-04-04)Oṣù Kẹrin 4, 1928
St. Louis, Missouri, U.S.
Ọjọ́ aláìsíMay 28, 2014(2014-05-28) (ọmọ ọdún 86)
Winston-Salem, North Carolina, U.S.
Iṣẹ́Poet, civil rights activist, dancer, film director, film producer, television producer, playwright, author, actress, professor
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
Ẹ̀kọ́California Labor School
Alma materGeorge Washington High School
Literary movementCivil rights
Years active1957-2014
Website
http://www.mayaangelou.com

Maya Angelou (play /ˈm.ə ˈænəl/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Marguerite Annie Johnson; April 4, 1928May 28, 2014) jẹ́ olùkọ̀wé àti eléwì àpilẹ̀kọ ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà.[1] O di gbajúmọ̀ lórí àwọn ìwé tí ó kọ nípa ìgbésí-ayé ara-ẹni rẹ̀ mẹ́fà tó kọ tí wọ́n sì dá lórí ìgbà èwe àti ìgbà ọdọ́ rẹ̀. Àkọ́kọ́ nínú àwọn ìwé náà ni: I Know Why the Caged Bird Sings[2]tí ó kọ ní ọdún (1969), èyí dà lórí ìgbà èwe rẹ̀ títí dé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún. Ìwé rẹ̀ yí jẹ́ kó di gbajúmọ̀ káàkiri ayé, wọ́n yàn án fún àmì ẹ̀yẹ Ẹ̀bùn Ìwé Orílè-ẹ̀dẹ̀ Améríkà. O tí gbà ìwé ẹ̀rí àmì ẹ̀ye bí ọgbọ̀n, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n dá orúkọ rẹ̀ fún ẹ̀bùn Ẹ̀bùn Pulitzer fún ìwé ewì 1971 re, Just Give Me a Cool Drink of Water 'Fore I Diiie.[3]



  1. "Maya Angelou". Biography. 2018-02-28. Retrieved 2020-04-04. 
  2. "Caged Bird Legacy". The Legacy of Dr. Maya Angelou. 2020-03-04. Retrieved 2020-04-04. 
  3. Provan, Alexander (2020-04-04). "Maya Angelou". Poetry Foundation. Retrieved 2020-04-04.