Jump to content

Louise Beavers

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Louise Beavers (March 8, 1902 – October 26, 1962)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin fíìmù agbéléwò àti tẹlifíṣọ́ọ̀nù ní Orílẹ̀ èdè Amerika. Láti ọdún 1920 sí ọdún 1960, ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àti ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù méjì tó gbajúmọ̀ jù lọ. Ẹrú tàbí ọmọ-ọ̀dọ̀ ni wọ́n sábà máa ń lò ó fún nínú àwọn eré náà.[2]

Louise Beavers àti Carole nínú fíìmù Made for each other

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. She was listed with her parents on the 1900 Federal Census as having been born in March 1900
  2. Gates, Henry Louis. Africana: arts and letters: an A-to-Z reference of writers, musicians, and artists (2005), p. 71; ISBN 0-7624-2042-1