Lorraine Hansberry
Ìrísí
Lorraine Hansberry | |
---|---|
Iṣẹ́ | Playwright, author |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Ẹ̀kọ́ | The New School |
Lorraine Hansberry (May 19, 1930[1] – January 12, 1965) je omo Afrika Amerika akoere ati afowokowe awon oro oloselu, leta, ati aroko.[2] Iwe re to gbajumojulo, A Raisin in the Sun, wa lati ibi wahala awon ebi re nile-ejo nitori ofin eleyameya igbele ni Apa Washington Park ti South Side Chicago nigba to wa lomode.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Carter 1980, p. 40.
- ↑ Lipari, Lisbeth. "Queering the borders: Lorraine Hansberry’s 1957 Letters to The Ladder" Paper presented at the annual meeting of the International Communication Association, Marriott Hotel, San Diego, CA, May 27, 2003 Online <.PDF>. 2008-06-28 <http://www.allacademic.com/meta/p112109_index.html Archived 2020-04-05 at the Wayback Machine.>
- ↑ Carter, Stephen R., Commitment Amid Complexity: Lorraine Hansberry's Life in Action, MELUS (The Society for the Study of the Multi-Ethnic Literature of the United States), Vol. 7, Issue 3, at 39,40-41 (Autumn 1980), available at <http://www.jstor.org/stable/467027> (subscription required).