Ida B. Wells
Ìrísí
Ida Bell Wells-Barnett (July 16, 1862 – March 25, 1931) je omo Afrika Amerika oniroyin, olootu iwe-iroyin ati, pelu oko re Ferdinand L. Barnett,[1] ikan ninu asiwaju akoko fun Egbe irinkankan eto omoolu. O se akosile bi Idajopaniyan ni orile-ede Amerika se sele, be sini o kopa ninu egbe irinkankan fun awon eto obinrin ati egbe irinkankan fun eto didibo fun awon obinrin.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |