Jump to content

Harry Belafonte

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Harry Belafonte
Belafonte at the 2011 Tribeca Film Festival Vanity Fair party
Belafonte at the 2011 Tribeca Film Festival Vanity Fair party
Background information
Orúkọ àbísọHarold George Bellanfanti, Jr.
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹta 1927 (1927 -03-01) (ọmọ ọdún 97)
Harlem, New York, U.S.
Irú orinCalypso, vocal, folk
Occupation(s)Actor, activist, singer
Years active1949–2003
LabelsRCA Victor
CBS
EMI
Island

Harold George "Harry" Belafonte, Jr. (March 1, 1927 - April 25, 2023) je akorin, osere ati ati alakitiyan awujo ara Amerika. O je pipe bi "Oba Orin Calypso" fun imugbajumo iru orin Caribbean kakiri aye ni ewadun 1950. Belafonte gbajumo fun kiko orin "The Banana Boat Song", pelu igbe-orin "Day-O." Kakiri ise re o je agbejero fun eto araalu ati ija omoniyan.