Jump to content

Beyoncé Knowles

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Beyoncé Knowles
Knowles in 2013
Knowles in 2013
Background information
Orúkọ àbísọBeyoncé Giselle Knowles
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹ̀sán 1981 (1981-09-04) (ọmọ ọdún 43)[1]
Ìbẹ̀rẹ̀Houston, Texas, United States
Irú orinR&B, pop, soul, hip hop
Occupation(s)Singer, songwriter, record producer, actress, dancer, entertainer, choreographer, model, video director
Years active1997–present
LabelsColumbia
Associated actsDestiny's Child, Jay-Z, Solange Knowles
Websitebeyonceonline.com

Beyoncé's autograph

Beyoncé Giselle Knowles (play /biˈjɒns/ bee-YON-say; bíi Ọjọ́ kẹrin Oṣù kẹsán Odún 1981), tí wọ́n mọ̀ sí Beyoncé jẹ́ alágbe tí ó ń kọ R&B àti ẹlẹ́ṣọ́ aṣọ ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Wọ́n bíi ní Houston ní Texas, níbi tó ti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọnà síṣe. Knowles kọ́kọ́ gbajúmọ̀ ní òpin èwádún 1990 gẹ́gẹ́ bí asíwájú akọrin ẹgbẹ́ olórin R&B Destiny's Child, ìkan nínú àwọn ẹgbẹ́ olórin lóbìnrin tí ó tàjùlọ lágbáyé.

  • Dangerously In Love (2003)
  • B'Day (2006)
  • I Am... Sasha Fierce (2008)
  • 4 (2011)
  • Live at Wembley (2004)
  • The Beyoncé Experience Live (2007)
  • I Am... Yours: An Intimate Performance at Wynn Las Vegas (2009)
  • I Am... World Tour (2010)
  • Live at Roseland (2011)
  • Crazy In Love (ft. Jay-Z) (2003)
  • Baby Boy (ft. Sean Paul) (2003)
  • Me, Myself And I (2003)
  • Naughty Girl (2004)
  • Check On It (2005)
  • Déjà Vu (ft. Jay-Z) (2006)
  • Ring the Alarm (2006)
  • Irreplaceable (2006)
  • Beautiful Liar (2007)
  • Get Me Bodied (2007)
  • Green Light (2007)
  • If I Were a Boy (2008)
  • Single Ladies (2008)
  • Diva (2009)
  • Halo (2009)
  • Ego (2009)
  • Sweet Dreams (2009)
  • Broken-Hearted Girl (2009)
  • Video Phone (2009)
  • "Why Don't You Love Me" (2009)
  • Run the World (Girls) (2011)
  • Best Thing I Never Had (2011)
  • Countdown (2011)
  • Love On Top (2011)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]