50 Cent
50 Cent | |
---|---|
50 Cent at the 2009 American Music Awards | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Curtis James Jackson III |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Keje 1975[1] |
Ìbẹ̀rẹ̀ | South Jamaica, Queens, New York, I.A.A. |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | Rapper |
Years active | 1997–present |
Labels | Shady, Aftermath, Interscope |
Associated acts | G-Unit, Dr. Dre, Eminem, Sha Money XL |
Website | 50cent.com |
Curtis James Jackson III (ọjọ́ ìbí Oṣù Kéje 6, 1975), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ 50 Cent, jẹ́ ará Amẹ́ríkà olórin tàkásufé, olùtajà, olùdókòòwò, atọ́kùn àwo orin, àti òsèré. Ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí àwọn àwo rẹ̀ "Get Rich or Die Tryin'" (2003) ati "The Massacre" (2005) jade. "Get Rich or Die Tryin'" ti gba ìwé-ẹ̀rí platinum mẹ́jọ láti ọwọ́ RIAA.[2] Àwo rẹ̀ "The Massacre" gba ìwé-ẹ̀rí platinum máàrún láàtı ọwọ́ RIAA.[2]
Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wón bí Jackson ní Queens, ìlú New York, tí Sabrina tí se ìyá rẹ tọ dàgbà ni Jamaika.[3]
Ó bẹ̀rẹ̀ sí n ja ijaelese ni ọmọ ọdún mọ́kànlá. Ní ọmọ ọdún méjìlá, ó bẹ̀rẹ̀ si nta ògùn olóró nígbà tí awọn òbí òbí rẹ ro wípé o wa ní ilé ẹ̀kọ́.
Àkójọ awọn ẹ̀bùn àmì ẹyẹ atí àyẹ́sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]American Music Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]50 Cent gbà ẹbùn àmì ẹyẹ méta nínu mefa ti wọn ti pe ni American Music Awards ọlọ́dọdún.[4][5]
Ọdún | Àkọ́ọ́lé | Ẹ̀bùn | Èsì |
---|---|---|---|
2003 | Get Rich or Die Tryin' | Favorite Rap/Hip-Hop Album | Gbàá |
50 Cent | Favorite Rap/Hip-Hop Male Artist | Gbàá | |
Fan's Choice Award | Wọ́n pèé | ||
2005 | The Massacre | Favorite Rap/Hip-Hop Album | Gbàá |
50 Cent | Favorite Pop/Rock Male Artist | Wọ́n pèé | |
Favorite Rap/Hip-Hop Male Artist | Wọ́n pèé |
Rhythm & Soul Music Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́ọ́lé | Ẹ̀bùn | Èsì |
---|---|---|---|
2004 | 50 Cent | Songwriter of the Year3 | Gbàá |
"In da Club" | Top R&B/Hip-Hop Song | Gbàá | |
"In da Club" | Top Rap Song | Gbàá | |
2005 | "In da Club" | Top Ringtone Song of the Year | Gbàá |
2006 | 50 Cent | Songwriter of the Year4 | Gbàá |
"How We Do" | Top Rap Song | Gbàá | |
"Candy Shop" | Ringtone of the Year | Gbàá |
BET Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́ọ́lé | Ẹ̀bùn | Èsì |
---|---|---|---|
2003 | 50 Cent | Best New Artist | Gbàá |
Best Male Hip-Hop Artist | Gbàá | ||
2004 | 50 Cent | Best Male Hip-Hop Artist | Wọ́n pèé |
G-Unit | Best Group | Gbàá | |
"Hate It or Love It" | Best Collaboration | Wọ́n pèé | |
2005 | 50 Cent | Best Male Hip-Hop Artist | Wọ́n pèé |
2006 | 50 Cent | Best Hip-Hop Artist | Wọ́n pèé |
Best Male Hip-Hop Artist | Wọ́n pèé |
BET Hip Hop Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́ọ́lé | Ẹ̀bùn | Èsì |
---|---|---|---|
2007 | 50 Cent | Hustler of the Year | Gbàá |
"I Get Money" | Track of the Year | Wọ́n pèé | |
Best Hip Hop Video | Wọ́n pèé | ||
2008 | 50 Cent | Hustler of the Year | Wọ́n pèé |
2009 | Thisis50 | Best Hip Hop Online Site | Wọ́n pèé |
2010 | Thisis50 | Best Hip Hop Online Site | Wọ́n pèé |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "How old is 50 Cent?". Capital XTRA. November 1, 2018. Archived from the original on November 18, 2022. Retrieved November 18, 2022.
- ↑ 2.0 2.1 "50 Cent Film Offers New Version of Rapper – Celebrity Gossip | Entertainment News | Arts And Entertainment". Fox News. November 7, 2005. http://www.foxnews.com/story/0,2933,174864,00.html. Retrieved May 12, 2010.
- ↑ Hattenstone, Simon (May 4, 2020). "50 Cent on love, cash and bankruptcy: ‘When there are setbacks, there will be get-backs’". the Guardian. Retrieved November 18, 2022.
- ↑ 31st American Music Awards Archived November 22, 2016, at the Wayback Machine.. Rock on the Net. Accessed on June 16, 2007.
- ↑ 33rd American Music Awards Archived November 22, 2016, at the Wayback Machine.. Rock on the Net. Accessed on June 16, 2007.