Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹjọ
Ìrísí
Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹjọ: Ọjọ́ ìlómìnira ní Ukréìn (1991)
- 1909 – Àwọn òsìṣẹ́ bẹ̀rẹ̀ síní kó sìmẹ́ùntì fún Ìladò Panamá
- 1912 – Alaska di ilẹ̀agbègbè orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1937 – M.K.O Abiola olóṣẹ̀lú àti oníṣòwò ará Nàìjíríà (al. 1998)
- 1947 – Paulo Coelho, olukowe ara Brazil
- 1963 – Peter Rufai, agbaboolu-elese ara Naijiria
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1921 – Nikolay Gumilyov, ako-ewi ara Russia (ib. 1886)
- 1943 – Antonio Alice, onise-ona ara Argentina (ib. 1886)
- 1954 – Getúlio Vargas, oloselu ara Brazil, Aare ile Brazil 17k (ib. 1882)