Pierre Curie
Ìrísí
Pierre Curie | |
---|---|
Pierre Curie | |
Ìbí | 15 May 1859 Paris, France |
Aláìsí | 19 April 1906 Paris, France | (ọmọ ọdún 46)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | French |
Pápá | Physics |
Ibi ẹ̀kọ́ | Sorbonne |
Doctoral students | Paul Langevin André-Louis Debierne Marguerite Catherine Perey |
Ó gbajúmọ̀ fún | Radioactivity |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1903) |
Pierre Curie (15 May 1859 – 19 April 1906) je omo orile-ede Fransi to je onimo fisiyiki, asiwaju ninu kristalografi, isegberingberin, piezoelectricity ati radiolilagabra, ati elebun Nobel. Ni 1903 o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki pelu iyawo re, Maria Skłodowska-Curie, ati Henri Becquerel, "fun idamo ise pataki ti won se nipa iwadi papo won lori isele itankakiri ti Ojogbon Henri Becquerel se awari."
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |