Afidimule awon Onimose-ero Onitanna ati Ero-aloitanna
Ìrísí
Irú | Àgbájọ Alágbàṣe |
---|---|
Dídásílẹ̀ ní | January 1, 1963 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Merger of the American Institute of Electrical Engineers and the Institute of Radio Engineers |
Òṣìṣẹ́ | Dr. John R. Vig, current president |
Area served | Kakiriaye |
Focus | Electrical, electronics, and information technology[1] |
Method | Industry standards, Conferences, Publications |
Revenue | US$330 million |
Members | 365,000+ |
Ibitàkun | www.ieee.org |
IEEE to duro lede Geesi fun Institute of Electrical and Electronics Engineers (Afidimule awon Onimose-ero Onitanna ati Ero-aloitanna) je agbajo alagbase aije fun ere kariaye fun ilosiwaju onaimuse to je mo itanna.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |