Brad Pitt

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Brad Pitt jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé àti atọ́kùn eré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ẹ̀bùn akádẹ́mì lẹ́ẹ̀mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí olùgbéjáde eré lábẹ́ ilé iṣẹ́rẹ̀, Plan B Entertainment. Pitt kọ̣́kọ́ di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bíi darandaran nínú eré Thelma & Louise (1991).[1][2]

Brad Pitt
Pitt smiling
Brad Pitt - Hollywood California - July 2019
Ọjọ́ìbíWilliam Bradley Pitt
18 Oṣù Kejìlá 1963 (1963-12-18) (ọmọ ọdún 60)
Shawnee, Oklahoma, U.S.
Iṣẹ́Actor, producer
Ìgbà iṣẹ́1987–present
Olólùfẹ́
Jennifer Aniston
(m. 2000; div. 2005)

Angelina Jolie (m. 2014)
Àwọn ọmọ6
Àwọn olùbátanÀdàkọ:Plain list

Àwọn eré tí ó ti kópa

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe