This document describes the origins of ori (destiny) and the roles it played in creating various orisha and lands. It also contains a prayer to Ifa from the divination system asking for guidance and blessings. The prayer references how Ifa can teach and help one avoid harm if its wisdom is followed. It concludes with a saying about Osun, the orisha of water, rivers, and fertility.
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
0%(1)0% found this document useful (1 vote)
944 views2 pages
Ori From Ejiogbe
This document describes the origins of ori (destiny) and the roles it played in creating various orisha and lands. It also contains a prayer to Ifa from the divination system asking for guidance and blessings. The prayer references how Ifa can teach and help one avoid harm if its wisdom is followed. It concludes with a saying about Osun, the orisha of water, rivers, and fertility.
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
You are on page 1/ 2
Ori from ejiogbe :
ogbirigidi nii ja toke lule
a difa fun alagbede okun laa pe ori ori lo da oya si ile ira ori lo da sango si koso ori lo da orisa nla si iranje ori lo da ogun sode ire ori lo da esu odara sode ketu ori lo da osun si ijumu ori lo da orunmila si oke igeti gbogbo isowo ope,ibi ori da misi yi dara
ori da misi yi dara
translation
a loud sound is heard when an object falls down cast divination for the blacksmith of the ocean called ori oridestinycreated oya in the land of ira oridestinycreated sango in the land of koso oridestinycreated obatala in the land of iranje ori destinyridestinycreated ogun in the land of ire oridestinycreated obatala in the land of iranje ori destinycreated esu in the land of ketu oridestinycreated osun in the land
prayer ifa from iwori meji: eni a ba wade la a ba rele eni aja ba wa ni aja un a lo a difa fun ejiwori e yi ti yio teju mo akapo re giri giri ifa teju mo mi ko wo mi ire, ejikoko iwori ti o ba teju moni a maa lowo lowo ejikoko iwori,ifa teju mo mi ko wo mi ire tio ba teju mo ni amaa laya ,a ma loko ejikoko iwori,ifa teju mo mi koo wo mi ire ti o ba teju mo ni, a mo bimo ni, a mo bimo ejikoko iwori, ifa teju mo mi ko wo mi ire ti o ba teju mo ni ,a maa kole eji koko iwori,ifa teju mo mi ko wo mi ire,ejikoko iwori ti o ba teju mo ni,a ma nire gbogbo,eji koko iwori,ifa teju mo mi ko wo mi re,eji koko oturarosun: fese mejeji se bamubamu ki yanrin odo mole adifa fun otuamosun ti yio fi osun le iku lo ki la fi le iku lo igbayi o otuamosun la fi leku lo
Scientific Pilgrimage: ‘The Life and Times of Emeritus Professor V.A Oyenuga’. D.Sc, Fas, Cfr Nigeria’S First Emeritus Professor and Africa’S First Agriculture Professor.